Adura yoruba |
Baba wa ti nbe li orun Mt3:17 Ohun kan lati orun wa ti o wi pe eyiyii ni Ayanfe omo mi Eni ti inu mi dun si gidigidi Mt4:4 nko fe wa laye nipa akara nikan emi fe wa laye nipa gbogbo oro ti o ti enu Olorun jade wa Mt4;6 nko fe be sile fun ara mi Mt4:7 nko fe dan Oluwa Olorun mi wo Mt4:9 nko fe wole fun satani Nko fe foribale fun satani Mt4:10 emi fe ki satani pada lehin mi pada lehin mi, satani Oluwa Olorun mi ni mo fe foribale fun Oluwa Olorun mi nikansoso ni mo fe maa sin Mt4:11 fi mi sile, satani emi fe ki awon angeli se iranse fun mi Mt4:17 mo fe ronupiwada Mt4:19 mo fe to Jesus lehin Mo fe ki Jesu so mi di apeja enia Mt4:25 mo fe ki opolopo enia to Jesus lehin Mt5:3 mo fe ni ijoba Olorun Mt5;4 mo fe maa kaanu Mo fe ki Olorun tu mi ninu Mt5:5 mo fe ki okan mi tutu Mo fe jogun aiye Mt5:6 mo fe tele ododo mo fe yo Mt5:7 mo fe je alaanu Mo fe ri aanu gba Mt5:8 Mo fe ki inu mi funfun emi fe ri Olorun Mt5:9 emi fe je onilaja emi fe ki a ma a pe mi ni omo Olorun Mt5:12 mo fe maa yo emi fe kun fun ayo emi fe ki ere mi po li orun Mt5:13 emi ni iyo aiye Nko fe di obu Adun ni mi emi fe nilaari Nko fe ki a da mi nu Nko fe di itemole ni atelese eniyan Mt5:14 Emi ni imole aiye Ori oke ni mo wa Mi o le farasin Mi o fe farasin Mt5:15 fitila ni mi Mi o le wa labe osuwon Ori opa fitila ni mowa emi nfi imole fun gbogbo eniyan ti nbe ninu ile Mt5:16 emi fe je ki imole mi ki o mole to bee niwaju eniyan emi fe ki awon eniyan maa ri ise rere mi emi fe ki awon eniyan maa yin baba mi ti nbe li orun logo Nko fe ro pe Jesu wa lati pa ofin run Nko fe ro pe Jesus wa lati pa awon woli run Mt5:19 nko fe ru okan kikini ninu ofin Olorun Nko fe ko awon eniyan lati ru ofin Olorun Mt5:20 emi fe ki ododo mi koja ododo awon akowe ati ti awon farisi emi fe de ijoba orun Mt5:21 nko fe paniyan Mt5:22 Nko fe binu nko fe wa ninu ewu idajo nko fe wa ninu ewu igbimo Nko fe wa ninu ewu ina orun apaadi Mt5:23 nko fe ki arakunrin mi ni ohun kan ninu si mi Mt5:24 emi fe koko ba arakunrin mi laja Mt5:25 nko fe ki ota mi fi mi le onidajo lowo Nko fe ki a gbe mi so sinu tuubu Mt5:26 emi fe jade kuro ninu tuubu Mt5:27 Nko fe se pansaga Mt5:28 nko fe wo obinrin kan lati se ifekufe si i Nko fe se pansaga ni okan mi Mt5;29 emi fe yo ikose ti o wa ni oju mi jade emi fe so ikose ti o wa ni oju mi nu emi fe ki ikose ti o wa ni eya ara mi segbe Nko fe ki a gbe gbogbo ara mi ju sinu ina orun apadi Mt5:30 nko fe ki owo mi mu mi kose emi fe ge Ikose ti o wa ni owo mi kuro Mt5:31 nko fe ko aya mi sile Nko fe mu aya mi se pansaga Nko fe gbe eni ti a ko sile ni iyawo Mt5:34 nko fe bura rara Nko fe fi orun bura Mt5:35 nko fe fi aiye bura Mt5:36 nko fe fi ori mi bura Mt5:37 nko fe so oro ti o wa nipase ibi Mt5:41 emi fe ba eniti o fi agbara mu mi lo si ibuso kan, de ibuso meji Mt5:42 emi fe fi fun eniti o bere lowo mi Nko fe mu oju kuro lodo eni ti o nfe ya lowo mi Mt5:43 nko fe korira awon ota mi Mt5:44 emi fe sure fun awon eni ti o nfi mi re emi fe soore fun awon ti o korira mi emi fe gbadura fun awon ti nfi arankan ba mi lo emi fe gbadura fun awon ti nse inunibini si mi Mt5:48 emi fe pe gege bi baba mi ti nbe li orun ti pe Mt6:9 Baba wa ti nbe ni orun Ki a bowo fun oruko re Mt6:10 Ki ijoba re de Ife tire ni ki a se, bii ti orun, bee ni ni aye Mt6:11 Fun wa ni onje oojo wa loni Mt6:12 Dari gbese wa ji wa, bi awa ti ndariji awon onigbese wa Mt6:13 Ma se fa wa sinu idewo, sugbon gba wa lowo bilisi Nitori ijoba ni tire, ati agbara, ati ogo, laelae Ni oruko Oluwa jesu kristi Rev1:8 Alfa ati Omega Ipilese ati opin Eni ti o nbe, ti o ti wa, ti o si nbowa Olodumare Rev1:17 eni isaaju ati eni ikehin Rev1:18 eni ti o nbe laaye si i titi lae Eni ti o ni kokoro iku ati ti isa -oku Jn17:11 baba mimo, pa mi mo, loruko re Jn17:12 Ma je ki nsegbe Jn17:13 Je ki ayo Jesu ni imuse kikun ninu emi tikarami Jn17:15 pa mi mo kuro ninu ibi Jn17:17 So mi di mimo ninu otito Otito ni oro re |
Thursday, February 23, 2017
First Love Bible Church: faith
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
No comments:
Post a Comment